PHOTO: Dre San- "Ijo Ope Lyrics"

 This is a new hit by Dre San, titled “ijo Ope”; delivered in Yoruba language, meaning “Dance of Thanks-giving”. This is a wonderful, danceable song. Here is the lyrics below.

(PRELUDE/HOOK)

Huhh; omo olope, t’o ba gb’ope
Je ka Jijo Ope; call me Dre San
Mo fe Jijo Ope, mo fe Jijo Ope, mo ti sa’se gbope
Omo olope gbope; omo olope sope [s’ope]

(CHORUS)

Awa arawa ri’ra wa; Awa ara wa ri’ra wa
Olokete r’omo ekun; awa arawa ri ra wa
Olosho t’o ri Rosco; awa arawa ri ra wa
Se tori pe mo l’owo? [Mo l’owo] Se tori pe mo l’ola?
S’o fe f’apo mi ya? S’o fe f’apo mi ya?

Ma m’owo lo be o; ma m’owo lo be o

(HOOK 2)

Mo fe Jijo Ope, mo fe Jijo Ope, mo ti sa’se gbope
Omo olope gb’ope; [gb’ope]
Eyin omoge sukerere; eyin omoge e fa kerere
Oya su kererere; fa kererere; suke; suke; fa nkan; gba nkan
Tinko; tinko; tinko; tinko
Tinko; tinko; tinko; tinko; tinko; tinko

(HOOK 1)

Mo fe Jijo Ope, mo fe Jijo Ope, mo ti sa’se gbope
Omo olope gbope; omo olope s’ope [s’ope]

(CHORUS)

Awa arawa ri’ra wa; awa arawa ri’ra wa
B’Ologini r’omo ekun; awa arawa ri’ra wa
Olosho t’o ri Rosco; awa arawa ri’ra wa
Se tori pe mo l’owo? [Mo l’owo] Se tori pe mo l’ola?
S’o fe f’apo mi ya? S’o fe f’apo mi ya?

Ma m’owo lo be o; ma m’owo lo be o

(HOOK 2)

Mo fe Jijo Ope, mo fe Jijo Ope, mo ti sa’se gbope
Omo olope gb’ope; [gb’ope]
Eyin omoge sukerere; [yebe] eyin omoge e fa kerere
Oya su kererere; fa kererere; suke; suke;
fa nkan, gba nkan [huh huuh]

(VERSE 1)

Omo to ba s’ishe; [s’ishe]
Abi eyi to sa ‘she; [sa ‘she]
T’o ba ti gbope; [gbope], o ye k’o ma dupe; [dupe]
T’o ba ti sa she gbope o; oye ko ma jijo gbope
To ba ti sa she lowo oo; ko ma sana wole oo
Ti won ba fe gbe owo epo wa oo,ko ni biko; biko; biko; ogini? Biko
Lepa biko ;biko; biko; orobo biko; biko; biko  [biko]
Ni igbayen nobody know me [know me];
Nisinyi gbogbo won mo mi [mo mi]
Gucci, Bugatti, Ferrari [Ferrari]
Talo so pe ko si ijo? ijo nbe lese wa
Talo sope ko si owo? owo nbe lapo wa o

(HOOK 1)

Mo fe Jijo Ope, mo fe Jijo Ope, mo ti sa’se gbope
Omo olope gbope; omo olope s’ope [s’ope]

(CHORUS)

Awa arawa ri’ra wa [eh ehh]; awa ara wa ri’ra wa [eh ehh]
B’Ologini r’omo ekun; awa arawa ri’ra wa
Olosho t’o ri Rosco; awa arawa ri’ra wa [yeh]
Se tori pe mo l’owo? [Mo l’owo] Se tori pe mo l’ola?
S’o fe f’apo mi ya? S’o fe f’apo mi ya?
Ma m’owo lo be o; ma m’owo lo be o

(HOOK 2)

Mo fe Jijo Ope, mo fe Jijo Ope, mo ti sa’se gbope
Omo olope gb’ope; [yeh; gb’ope]
Eyin omoge sukerere; [sukerere o] Eyin omoge e fa kerere [fakerere]
Oya su kererere; fa kererere; suke; suke;
fa nkan, gba nkan
Tinko; tinko; tinko; tinko

Tinko; tinko; tinko; tinko; tinko; tinko….

Suggested:   DOWNLOAD AUDIO: Dre San- "Ijo Ope"

(FINALE)

Yeh; yeh
Call me Dre San; mama; Naija Oxygen
Yeye; iyeh yeh; yeh yeh; yeh yeh;
Yeh yeh
==It’s Dre San on the mix==

[MUSIC LYRICS]: Dre San- “Ijo Ope”

Tino9nMUSIC LYRICSDre San,Ijo Ope Lyrics
 This is a new hit by Dre San, titled 'ijo Ope'; delivered in Yoruba language, meaning 'Dance of Thanks-giving'. This is a wonderful, danceable song. Here is the lyrics below. DOWNLOAD Mp3 AUDIO (PRELUDE/HOOK) Huhh; omo olope, t'o ba gb'ope Je ka Jijo Ope; call me Dre San Mo fe Jijo Ope, mo fe Jijo...